ORO DOJU E!! Oriyomi Hamzat, Awon CAN Faraya; Muyideen Agbala Gabriel ati Awon Alfa Pada Sesin

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 20 жов 2024

КОМЕНТАРІ • 64

  • @AkinropoOlasoji
    @AkinropoOlasoji 2 місяці тому

    Olorun a ma gba wa o. A ko ni sore se.Alfa..., keep the good job up. E ko ni si se o.

  • @graceolarewaju8838
    @graceolarewaju8838 2 місяці тому +8

    Ise owo oriyomi ni yen

  • @adebayophilip6011
    @adebayophilip6011 2 місяці тому +7

    Muyideen and those ones teaching him against Agbala Gabriel will no see peace and all those teaching muyideen against Amusan Gabriel will fail forever

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому +2

    Muyideen olorun koni se e ni omo awa abiyamo toto .enikeni eniakenia tio ba tun surport Muyideen koni se rere mo loke erupe ni agbara olorun amin

  • @DasolaTurayo-gc1tz
    @DasolaTurayo-gc1tz 2 місяці тому

    Koni da fun e muyideen omo tani o kise omo temi iya egbe mo iye omo ti o bi aye e dema baje ni tani o ma spot ewe eleyi yiyo ole ole omo ale olori buruku ni e muyideen ati awon alatileyi eniri batise eni rona gbegba ofo ni gbogbo yi mase iwo ti nkan ti se emi e alfa olorun toto alfa eni somo nu eni damu alfa eku ise oluwa olorun ma pinyi lere topo thank you so much sir

  • @fayehunatilola577
    @fayehunatilola577 2 місяці тому +1

    Alfa you and Alhaji Akeugbagold are God sent to preach peace and Love ❤️.
    Alfa God will continue to bless you as His servant

  • @yemisi5812
    @yemisi5812 2 місяці тому +3

    Oriyomi has bn trying to bring Agbala Gabriel down I'm the last three years. 2 time when Saheed Osupa bought Generator for Agbala. Oriyomi was not happy.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому +2

    Gbogbo eyin Daddy G.Os ati eyin pastors tie da school sile e so school yin di free school fun awon members yin .titthes and offerings yin e bere si nfun awon members yin ni onje ni every sunday ti e ba ko lati se be olorun yio ro ojo ibinu si ori gbogbo yin nitori e ko se ife olorun .gbogbo wealths tie ko jo ma sofo danu loju aiye yin ni oruko Jesu amin

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому +4

    Eyin enia mi ni ilu lbadan e ranti wipe alanu ni agbala Gabriel je ni ilu lbadan omo ilu lbadan ni mama pastor Gabriel Ademola Amusan of agbala Gabriel . Gbogbo eyikeyi ninu omo lbadan tio ndite pastor Gabriel koni pade alanu mo nitori lran ejo kin ri alanu.....

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому

    Gbogbo eyin tie nlo Muyideen against Agbala Gabriel lati jabo olorun yio ja gbogbo yin bo .olorun yio so gbogbo yin di eni ile ni oruko Jesu amin

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому +1

    Gbogbo eyin oloriburuku tie nlo Muyideen against Pastor Gabriel Ademola Amusan of agbala Gabriel e gbo oro ase lenu iku gbigbona loma pale yin mo ni agbara Olorun amin ase Edumare..

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому

    Gbogbo eyin ota pastor Gabriel Ademola Amusan of agbala Gabriel ofo lomi efo nse ofo ni gbogbo yin ma se danu ni agbara olorun amin ase Edumare

  • @elizabethmobolaji8847
    @elizabethmobolaji8847 2 місяці тому +1

    Alfa ayeyin adara,eo ni subu lailai baba iru Alfa bitiyin sowon,e continues sir,ohun timo mo ni wipe olorun agbeja pastor agbala Gabriel

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому +1

    Muyideen oloriburuku arungun omo .gbogbo owo oja ti Agbala Gabriel si fun e o fi owo na ta baba ljebu tan ..olorun ti pada leyin re Muyideen..o ko ni ri alanu mo ni agbara Olorun amin ase Edumare adabi ti kin ba se oore ni Agbala Gabriel se fun Muyideen nikan loku ase Edumare adabi ti kin ba se pastor Gabriel lo gbe e jade fun aiye ri nikan loku ase Edumare

  • @ditty6828
    @ditty6828 2 місяці тому

    😂😂😂😂 alfa Komaadun, adajo ma ni ki e shi lawani yin o, e ma tun lo da nkan mi sile o. 😂😂😂😂

  • @GbemisolaAjoke-m1k
    @GbemisolaAjoke-m1k 2 місяці тому

    Olorun abayinse lagbara olorun oju mati gbogbo won ni Amin god bless you sir

  • @sundaysolomon401
    @sundaysolomon401 2 місяці тому

    Alfa God bless you and your family

  • @oluwatoyinlogooluwaniyi7636
    @oluwatoyinlogooluwaniyi7636 2 місяці тому

    Alfa, emi yin a gun. Oju ko ni ti yin.E ku akitiyan sir. Otito yio leke lagbara Olorun.

  • @wolefam3792
    @wolefam3792 2 місяці тому

    Alabosi ni Oriyomi Hamzat! I knew from the get-go that he (Oriyomi Hamzat) was behind all this shenanigan, mischief-making. He, Oriyomi Hamzat had no intention of settling the issue between Muyideen and Agbala Gabriel. He went there purposely to retrieve the house document from Agbala Gabriel and give it to Muyideen. His second and more devilish mission was to humiliate Agbala Gabriel. What an evil sneaky person!

  • @adebayophilip6011
    @adebayophilip6011 2 місяці тому +2

    Awon Alfa ajigini and oriyomi will receive the judgement of Almighty Olodumare sooner except they confess all their evils against Agbala Gabriel

  • @abimbolaelufisan-p7v
    @abimbolaelufisan-p7v 2 місяці тому

    Egun idile ti wa lori Muyideen charger tele but now o tun ti wa po si bayi

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому +1

    Eyin enia mi ni ilu lbadan se e ranti ni lgbati Bola lge nse governor ni Oyo state se e ranti free health ati free school ati free books igbati awon oloriburuku kan di ota re ti won gbe Olunloyo si ipo governor omo wa ni e je kio se .kilo se fun wa ni ilu lbadan gbogbo governors tio ti o ti de ori ipo ewo ni a tun je anfani re bi ti Bola lge lati lgba yen
    E wo gbogbo awon arugbo ati alaini ti Agbala Gabriel nfun ni onje ninu ljo re ooo. E ma je ki Muyideen ko oriburuku tire ran awon enia miran ooo

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому

    Gbogbo eyin oloriburuku tie nlo Muyideen against Agbala Gabriel iran ejo kin pade alanu Gbogbo yin ati Muyideen koni ri tabi pade alanu mo tomotomo tiyawo tiyawo tebitebi taratara tirantiran ni agbara olorun amin ase Edumare

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому +1

    Muyideen olorun kin gbo adura oloriburuku afibisolore nitorina olorun koni gbo adura re ..

  • @wasiubakare3404
    @wasiubakare3404 2 місяці тому

    Another governor is coming to disgrace oriyomi hamzat

  • @olusolaogutuga208
    @olusolaogutuga208 2 місяці тому

    EJE KIWON GBE EJO YEN PADA WASI IBITI OTI SELE, GOD IS IN CONTROL

  • @OmolaraYusuf-kf3qt
    @OmolaraYusuf-kf3qt 2 місяці тому

    Lenu e muyideen. Ko gba enu fore father e

  • @yemisioladapo2011
    @yemisioladapo2011 2 місяці тому

    Abi oloriburuku ni iwo muyideen charger yi ni? omo awon melo? Ok you need another support abi atigbo, the support agbala gave you lodi wahala yi, so that you'll take us to zone 11 this is the beginning of yr problem. Alfa yoyin oro ooni wotan, oloriburuku somebody

  • @DasolaTurayo-gc1tz
    @DasolaTurayo-gc1tz 2 місяці тому

    Kini ogun were egba ni ogun were ti tori e ni won se na muyideen tori muyideen were ni igbo tiyi muyideen lori nkan ti pada se emi muyideen bayi

  • @funshoidowu1180
    @funshoidowu1180 2 місяці тому

    Mr kehinde, so you ca n sing like this, from Seattle

  • @fayehunatilola577
    @fayehunatilola577 2 місяці тому

    Olorun Oba lo nbinu si Muyideen nitori alaimore eda ni.
    Ibinu Olorun si sese bere l'ori Muyideen charger ni

  • @rachealatoyebi7893
    @rachealatoyebi7893 2 місяці тому

    Oriyomi mo pa .bi baba wa oriyomi o ba mo pe kan wa se pe fun gbogbo omo Nigeria

  • @christyshopade
    @christyshopade 2 місяці тому

    Muideen aiye nse e.Edi de ma mu e.Aiye e ti baje patapata

  • @OmolaraYusuf-kf3qt
    @OmolaraYusuf-kf3qt 2 місяці тому +1

    Muyideen will fail woefully, O ma sesin aworo

  • @victoriaoluwatosin322
    @victoriaoluwatosin322 2 місяці тому +1

    Olorun kosi leyin alabosi, alfa God bless you sir

  • @christianaholopade8690
    @christianaholopade8690 2 місяці тому

    Gbogbo eyin baba wa CAN. Edide. Eyin ono se se Traditional Edide. Eyin Alfa olododo. Edide. Ejeki ale ife. Ife gbodo wa larin wa. Edide de si Awon ti won fe ba aye je. Ti won nba ise Oluwa je. Edide Ki won le ki owo Ibaje bole. Ao fe iwa buruku bayii la wujo wa.

  • @Holllaoluwa2024
    @Holllaoluwa2024 2 місяці тому

    GABU ti si oore se
    Ore niwon
    Se Muyideen deserve a house ni? GABU answer pls
    If you are made the president, na so you go rule Nigeria?
    GABU ile ejo ya!!!
    “Ministry of house builder”
    You go learn!!!

  • @soyenkoyawerey
    @soyenkoyawerey 2 місяці тому

    HI

  • @ReginaSanyaolu
    @ReginaSanyaolu 2 місяці тому

    Afaa e see sir a dara fun yin ati iran di ran yin e o ni pade alagbako e o ni si ore se ooo

  • @leahayodele2526
    @leahayodele2526 2 місяці тому

    IWA LESIN. WHY TI WON SE LO SI OSOGBO..ALFA YIO DARA FUN YIN SIR.

  • @temitopebabade3732
    @temitopebabade3732 2 місяці тому

    Oloriburuku ni oriyomi hamzat ati muyideen. I have lost respect for oriyomi. Eni ibi ni

  • @ojoabuletagba6561
    @ojoabuletagba6561 2 місяці тому

    Alfa olorun olotito

  • @gafarhollajidex980
    @gafarhollajidex980 2 місяці тому

    This Alfa just complicating issues,
    Kuku become Christian so we would know you really love Agbala Gabriel.
    You are just looking for accolade from them.
    Stop ranting and let peace reign sir!

  • @OlusolaOgunnariwo
    @OlusolaOgunnariwo 2 місяці тому

    Ok This is a true Alfa of God

  • @adebankefalade5908
    @adebankefalade5908 2 місяці тому

    Alfa eyiti e se tito, e pe muyideen ki e ba wi, ki e pari gbogbo oro na ,

  • @SofeehatAkinbami
    @SofeehatAkinbami 2 місяці тому

    Afa alabosi ni yin

    • @yemisioladapo2011
      @yemisioladapo2011 2 місяці тому

      Which Alfa are you calling alabosi? I just want to know please thanks

    • @christyshopade
      @christyshopade 2 місяці тому

      Afa wo ni alabosi.?

  • @aminouadidja9057
    @aminouadidja9057 2 місяці тому

    Afa oni lani isoun atoko waba ileje gbogbp epe tiebase fun muidden gbogbo awon omo yi niko

    • @mhbj9902
      @mhbj9902 2 місяці тому +1

      Oloriburuku ni Iwo ti o ko atejise yi alaabo lakaye nie opolopo re si lo oti yawere awon Alfa alakatakiti nie afibisu more nie ati Muideen charger alaimore oloriburuku oponu tio Le ri Anu gba mo lailai

    • @kemoblunsky3794
      @kemoblunsky3794 2 місяці тому +2

      May you and your family have someone like muyideen in your life 🙏

    • @mhbj9902
      @mhbj9902 2 місяці тому +1

      Muideen charger alaimore yoyin begger epe ti mu ma lo si oja oje ki o lo ma se ise lo oponu olopolo Lilo were jatijati oloriburuku

    • @yemisioladapo2011
      @yemisioladapo2011 2 місяці тому

      I can see from yr comment that you're number 1 Boko Haram muslim hiding under religion.... oloriburuku onijagidijagan

    • @florenceadedeji3858
      @florenceadedeji3858 2 місяці тому +1

      Ofo lomi efo nse ofo loma se danu ni agbara olorun amin. You will not see favour in your life again in Jesus name amen

  • @GbemisolaAjoke-m1k
    @GbemisolaAjoke-m1k 2 місяці тому

    Olorun abayinse lagbara olorun oju mati gbogbo won ni Amin god bless you sir

  • @yemisioladapo2011
    @yemisioladapo2011 2 місяці тому

    Abi oloriburuku ni iwo muyideen charger yi ni? omo awon melo? Ok you need another support abi atigbo, the support agbala gave you lodi wahala yi, so that you'll take us to zone 11 this is the beginning of yr problem. Alfa yoyin oro ooni wotan, oloriburuku somebody