updates

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 19 вер 2024
  • updates

КОМЕНТАРІ • 23

  • @julianaomolayo5454
    @julianaomolayo5454 22 дні тому

    Iyalaje a ngbadun yin Jo, Ibaje enia ko le da ise Oluwa duro.
    E ma ba ise yin niso.
    Olorun Oba afi abo bo yin tomo tomo, ati oko ati ebi ni oruko Jesu Kristi
    Gbogbo enia ko lo foloju now
    Awon ti oni ogbon to tun ni oye ti won si tun ni imo, ma si wa laye yi dada.
    Iyalaje Ejowo e ma go on so un.

  • @julianaomolayo5454
    @julianaomolayo5454 22 дні тому

    Iyalaje a ngbadun yin Jo, Ibaje enia ko le da ise Oluwa duro. E ma ba ise yin niso. Gbogbo enia ko lafoju now. Awon ti oni ogbon to tun ni oye masi wa late dada. Iyalaje Ejowo e ma go on so in.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 23 дні тому +1

    Olusola Yusuf bio se fe kio ri fun Pastor Gabriel Ademola Amusan of agbala Gabriel be gege loma ri fun awon omo tire ni oruko Jesu amin adabi ti o ba je wipe oore ni Pastor Gabriel se fun Muyideen nikan loku ase Edumare

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 23 дні тому +1

    Iyalaje abiyamo toto God will protect you and your children in Jesus name amen.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 23 дні тому +1

    Olusola Yusuf olorun ma gbe ogun dide sie tomotomo ni agbara Olorun amin ase Edumare adabi tio ba je wipe iwo lo gbe Muyideen kuro ni abe bridge nikan loku.

  • @ogundairojolaade5577
    @ogundairojolaade5577 23 дні тому +1

    Hello iyalaje we all can see , do this deserve your explanation, please observe your grade, eniti ti o ba gbon ma moh nkan ton sele, omo iya min ride on don,t be stress please.

  • @ainafagbenro
    @ainafagbenro 23 дні тому +1

    Boya Olushola yusuff ti toast agbala Gabriel ri ti Agbala Gabriel ko lati fe, toripe emi ko mo ohun ti agbala ra ni'gba e

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 23 дні тому

    Olusola Yusuf ori re ti buru .eleda pastor Gabriel Ademola Amusan of agbala Gabriel loma seku pa e ni agbara olorun amin ase Edumare adabi tio ko ba bi awon omo tire nikan loku...

  • @adebimpesobande5292
    @adebimpesobande5292 23 дні тому +1

    Adajo agba, e ku ise takuntakun, Olorun a duro ti eyin na tomotomo.

  • @christianaholopade8690
    @christianaholopade8690 22 дні тому

    Olorun lo dii di yan Awon deciple meta fun agbala Gabriel. Mama wa Iyalaje. Baba wa komadun. Yahaya Gambari. Agbala Gabriel ko se eni kenı. En wo sun sun enba Loruko je. Ola run ko fe be. Baba ologun dudu. Ejeki afi ife ba ara wa lo. You don’t need part 3 sir. Esaw so fun Jakobu wipe sebi ara kan na ni awaa se. Ko si ere kan kan ni part 3 sir oruko aa kan ma baje si ni. Gbogbo yin pata ati baba ologun dudu. Anıyı Kaye niyin. İyi yin ko si ni baje lai lai. Egba gbe re pata pata. Agbala Gabriel. Agbala Gabriel the Angels were praising you pls hold your heart Ogun enu lasan ti ko le tu irin kan kan Lara re ni my dear. Eleyi ki se war front. We love yu too much. ❤❤🎉🎉😂

  • @GBEMILEKEODESESAN-jy7zt
    @GBEMILEKEODESESAN-jy7zt 23 дні тому +1

    Opololo olusola Yusuf yi ti lor 😂

  • @feliciashekoni5346
    @feliciashekoni5346 23 дні тому +1

    They just want the pastor to fall he will not fall God is with him they are just wicked and jealousy of the man of God.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 23 дні тому

    Olusola Yusuf ogun lakaye osinmole olomi nile feje we oni aso nile fi imokimo bora loma fi eje re we ni agbara olorun amin ase Edumare adabi tio ba je wipe oore ko ni agbala Gabriel se fun Muyideen nikan loku ase Edumare

  • @EuniceBunmi-nz5ly
    @EuniceBunmi-nz5ly 23 дні тому +2

    Awon alainiseee Alabosi

  • @olajumokeaworeni5882
    @olajumokeaworeni5882 22 дні тому

    Gbogbo ota Alagba Gabriel ati ota Iyalaje lo maa subu l'agbara Olorun. Amin.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 23 дні тому

    Olusola Yusuf enu orofo lon pa orofo enu re loma seku pa e ni agbara olorun amin ase Edumare adabi tio ba je wipe oore ko ni agbala Gabriel se fun Muyideen nikan loku ase Edumare

  • @favourolatunji9121
    @favourolatunji9121 22 дні тому

    Iyalaje e ku ise takun takun. Ti yin na a da t’omo t’omo ni oruko Jesu.
    That woman called Shola Yusuf is saying rubbish, that’s the nonsense they have been saying till they finished work and businesses in Nigeria today. Imagine she’s saying agriculture that other countries cherish and making their country rapidly growing, is not a good business.
    No wonder Nigeria is not moving forward. Her group should go and make things right, so that Nigeria can be healed as a whole.
    No one is interested in any part of ewi coming up, ok.
    Madam Sola go and stop the hate, bullying, harassment and violence please.

  • @victorogunleye2634
    @victorogunleye2634 22 дні тому

    I knew ologundudu(oloriburuku) will do this because I watched a video where he was interviewed to comment on agbala Gabriel /muyideen saga,his comment was bad

  • @EuniceBunmi-nz5ly
    @EuniceBunmi-nz5ly 23 дні тому +1

    Anreti part 10