ASẸ INU FUN AWỌN ỌJỌGBỌN TO DAJU

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 8 лют 2025
  • Hmm! ase inu yi je ọkan lara asiri ti awon wolii, pastor, babalawo tabi awon alfa ma n lo, mo fi n da yin loju wipe ti a ba fi ase yi sure fun eniyan tabi sẹ epe bi yoo se ri ni yen o, ẹ jẹ ki a ma ranti wipe a fi fila pa erin ojo kan soso lo niyi mọ o, nitori ki a le ma fi sure ni mo se fi sile kii se fun epe o

КОМЕНТАРІ • 20

  • @OkunowoAdelekesegun
    @OkunowoAdelekesegun Рік тому +1

    Aboru aboye sir

  • @ArowoloMiracle
    @ArowoloMiracle Місяць тому

    Thanks very much sir

  • @olomosolakehinde7856
    @olomosolakehinde7856 Рік тому

    Eseun gaani Baba! , E dakun e fun wa ni number yin sir

  • @AderemiObayemi
    @AderemiObayemi 4 місяці тому

    Thank you Sir

  • @kelanisaheed1539
    @kelanisaheed1539 Рік тому

    More blessings babami

  • @anthonysmith3720
    @anthonysmith3720 Рік тому

    Baba you're too much sir with the information you are disseminate to audience, i was so impressed with the way you attended to me last time when i called you with full respect. May the lord give you more wisdom and understand to lead us to the right way from Ekiti. I salute sir

  • @kolaafolabi8075
    @kolaafolabi8075 2 роки тому +2

    Thank so much sir

  • @olaoluwaoloyede8388
    @olaoluwaoloyede8388 2 роки тому +1

    Baba aku ewu odun opo e lao se laye , baba mo fe ise ti won fi nta motor ati eyi ti mo le fi ra motor, olorun yio ma wa pelu yio o, Amin

    • @omogiesitv
      @omogiesitv  2 роки тому +1

      Amin sir, odun ayo ni odun yi yoo je fun wa, ko si wahala sir, olohun oba yoo ma fi gbigba aduha si igbiyanju wa

    • @ARC.benedict-samson
      @ARC.benedict-samson 2 роки тому

      @@omogiesitv ejo sir se ele fun WA ni ise Eyonu NLA ati Awure pelu Osho Inu todaju e Jo sir.

  • @olomosolakehinde7856
    @olomosolakehinde7856 Рік тому

    ❤❤❤

  • @adigunakinrinade9917
    @adigunakinrinade9917 2 роки тому +1

    Eseun gan

  • @olalekanadebayo-rg5yk
    @olalekanadebayo-rg5yk Рік тому

    Eshebaba ewe aa maje funyin sir, number wo lale peyin si sir?

  • @sikiruolamiwale8840
    @sikiruolamiwale8840 2 роки тому

    God continues blessed you always

  • @folusayosamuel8506
    @folusayosamuel8506 2 роки тому

    Numba tiwon ma pe yin si. Tabi WhatsApp number yin

    • @omogiesitv
      @omogiesitv  2 роки тому

      Ko si video ti mo se jade ti ko si number mi nibe, 08061408254

    • @hammedkehinde
      @hammedkehinde 3 місяці тому

      Baba mi inu mi dun, e mu mi ranti baba mi, eti di baba fun mi lase Edumare e pe fun wa ma peyin