EYIN OBA ATI GOMINA OJU MA TI YIN LAIPE! ILU NIGERIA O TI PA RI(DRY/IYP)ILE YORUBA O TI DURO 5-7-24
Вставка
- Опубліковано 4 лип 2024
- EYIN OBA ATI GOMINA OJU MA TI YIN LAIPE! ILU NIGERIA O TI PA RI(DRY/IYP)ILE YORUBA O TI DURO
please guys don't forget to hit the subscribe button Thank you
Welcome to join the programme! Kindly Call This Whatsapp Number +353830243586 for any Information
DATE 5-7-2024
TIME 10:15Pm
#ijobaadele
#yorubanation
#yorubanation
#mrsmudupeonitirimkoabiola
#green4god
#green4godtv
#iyp
#dry
Make sure you LIKE SHARE SUBSCRIBE TO THE CHANNEL STAY SAFE and stay bless you - Розваги
Amin ase edunmare si gbogbo awon adura wa lase edunmare amin ase edunmare 🙏
EKU ise lran wa God bless you all 💯 ❤❤
Mo ki Mama wa MOA, Aare Olori Adele, gbogbo awon Adele ati gbogbo yin ti e nse ise Orile Ede Olominira Yoruba tiwa ntiwa. E ku ise takun takun. E seun gan ni o. Olorun a san yin ni esan rere o. Olorun a ba wa se ise naa ni asepe ni Oruko Jesu Kristi. Ase ye ati ase jere rere ni a o se ni oruko Jesu Kristi.
A ki nyin e seun pupopupo fun ise iran wa ooo. Olorun yi O san nyin ni esan agbara ati emi gigun.
Eku ise takuntakun