Yoruba Nation | Hausa ready for their own country
Вставка
- Опубліковано 28 вер 2024
- Yoruba Nation | Hausa ready for their own country
#tinubu #iroyin #sundayighoho #yorubanation #nigeria #fulaniherdsmen #arisetv #channelstv #obasolomoni #alaroyeonlinetv #agbalagabriel
Nigeria asi njoko bi Omo OSU meta, ATI RAKORO DEBI KI AMARIN OJUKAN NI NIGERIA SI WA.
AFE KURO NI LOCATION 419 NIG, KI ALE BERE SI NRIN KATUN MASARE LATI TUN ORILE EDE WASE.
Oju ko ni tiyin. Ao le lo si Nigeria.Oluwa a fun wa se. Oluwa a ba wa se.Lodo Oba.iba egbon Aaya.E ku ise takun takun.Nigeria yio Dara loju gbogbo Wa.
God bless you YORUBA youths and our papa Akintoye. Your struggles will never be in vain.. Yoruba Nation now now now now. Remain blessed.
Eku eto Ogbeni bobby
Awa omo Yoruba akise omo Nigeria
Ile tiya
Yoruba nation no going back
Prophet Ologun Loluwa,
Akiyin kabo baba wa eku ise wa Oluwa amuwa de ile ileri.
Evangelist ologun loluwa is the best ti won duro tan ati aaya.mowa gbaladura ni ashe edumare yoruba nasion ni afi ma ke happy new year.
Otito oro ni e so baba mi ologunloluwa, opo igba ni emi ma roo pe ki Olorun fun mi ni agbara lati se fun awon obayeje ile Yoruba.
Amin Asé Edumare 🤲 🙏 successful Is A Must Yoruba Nation soon close to us. kudos to you all ❤️❤️❤
Mo ki yin ogbeni Ologunloluwa aseye lalakan nsepo, e o se aseyori ni ase Eledumare amin
Ogbeni Bobby eku ise o. Kilode ti e o mu Aaya dani. 😂❤
Eku ipade olomole, awon alale a duro ti yin, Amin.
Amin. Aseeee .
Asake tv. E gboju ayo s'oke. 😂
Ekabo o Ogbeni Bobby e ku alejo
Aaya nle oo! O ku atotonu.
27:18 ❤
👏👏👏👏👏❤
Eku ise takun takun Ogbeni Bobby ati our prophet Ologunloluwa. God bless you all.
Ogbeni Bobby oye ki won toro fun aforiji lowo awa omo Yoruba.
Enibi ni Bola Tinubu tori ko fara mo ki Yoruba pin.
Ekale ooo God will see you through sir
😅
Owe po! 😅
🤣🤣🤣