Bawo ni ẹsin musulumi ṣe wa di ìjọba òṣèlú ile Nigeria, ọtọ l'ẹsin ọtọ ni ijọba. Ki awọn Musulumi lo so agbejẹ mọwọ ki wọn ma da ogun silẹ ni ilẹ yoruba.
They are using style ,if care is not taken,those people already knew that our amalgamation deal has expired,and now strategically trying to colonize us,we have to be seriously careful ooo,Isese agbewa ooo
God bless you . Ile orisa àti ise ni ile babanla wa. Eda ti wa ko ni gbabode ni ile Yoruba. Awon onile ko ni gba fun awon eni ẹ gbé wọn. Isese lagba. Ifa ni o bori . Ifa ni o bori gbogbo wọn. Awa o ni pofo a o ni rofo. Ifa a gba wa lowo eni ofo yi. Olodumare o ni jeka ri ibi àwọn ẹṣin pani pani
Eledumare oba adeda aseda o mama was pelu yin nigba kugba lore kore Lori oro akin ton ti enu yin jade lodi si Sharia law oriburuku ti won fe gbewa sile Yoruba ti kole sese rara ati rara Tani olorun you are a man of courage God we continue be with you
Kudos to you Tani Olohun, this is the kind of program you should be doing. All Emilokan people can clearly see that Ahmed Bola Tiefnubu is a born wasted Yoruba man, next election he should voted out of the office. This is Yorubaland, we are not Saudi or Muhammad slaves. Yorubaland belong to Isese.
Gbogbo orile-ede ni agbaye ti won ti n'se ofin Sharia awon orile-ede bee ki roju kii ra'ye won oo si ki ni ilosiwaju tobe jubee lo. E ku ise iran wa oo.❤❤
Lootó? Saudi Arabia: ko si ilu to ni óro ati ifayabalę ti o to ni gbogbo ile Larubawa. Malaysia: igbe aiye to dun to laarinrin ni awon ori’lę ede ngbe o. Bhurtan: awon ara ilu yi kii sé wahala rara ki wo to jęun. Qatar: gbogbo wa la mo wipe ilu to ni ęwa ati óro bi ilu yi s’ówon ni agbegbe rę. Indonesia: ko si wahala ati pakaleke ni oro awon omo ilu yi rara, ifayabalę nbę ni’bę ti o ju ti gbogbo agbanla aiyé lo… ati awon ilu bę bę lo ti nlo Shari’a ninu ofin ilu won!
You're liar. You forgot to mention Syria, Iraq, Iran and Pakistan. Definitely, Isese court and Christian court will be approved and there will be common of different laws. Is that what you want because it will leads to community war because all the religion sectors are also entitled to establish their courts.
you just listed the most beautiful, peaceful and progressive countries… until Western imperialists (who happens to also be Christian nations🙄) invaded, destroyed, looted and breed young men for terrorism in order to establish their own authority and influence in those countries! Deep down in your heart you know it’s true. If all religions want to establish their own individual customs and laws, as long as they don’t conflict with states laws, and what is naturally good for everyone, what’s the problem with that? Abi you don’t know that even state laws came from God’s laws ni?
Tani Olohun, I don't think the president and our Governors are in support of the Sharia court. Those people are stupid. Agba wole niti serin, akanmole niti eekan, aku sorinu niti adan, iran fulani, eru (slave) fulani ati awon alakatakiti esin omo yoruba o ni gberi mo ni ile yoruba lagbara Olodumare. Asee. More power to your elbow Prof. Tani Olohun. 👍 ❤❤❤
This is not a matter of suspension,no sharia law in Yoruba land,if you don’t want Religion war in Nigeria,both non radical Muslim,Christian and traditionalist will join their hands together to fight evil religion policy.
ori iya ati baba wa oo ni pada leyin wa ooo... ka mari ni! eewo orisa! Tani Olohun Aseda oo ni pada leyin re ooo! You are speaking on behalf of us all.
Sharia Court? the biggest and unimaginable Taboo to be mentioned in the entire Land of Yorubas, Kilo wa de ti Afojudi ati Arifin nla yii tie wa poju fun Iran Omo-Alade bayi? O mase o, sugbon ohun kan to daju ni wipe gbogbo randanrandan yi nbo wa di'tan laipe ojo. Tani Olorun e ku eto o, Ajinde Ara too maa je o.
Ekuise ooo eku eto klnse awon alfa yi tiwon ojeki ile yoeuba nlsinmi ilorin egbaki iseae se odun gemoja won esodi wahala mowon lowo efi olopa gbe won se eronu pe iru ojo bayi maawaye latise seria nile yoruba koleseesw ija lefe dasile
E se o Tani Olorun. Eyin Sotosoro E dide e gbohun soke o .Awon Alale ile Yoruba E dide o .E pa gbogbo Eni to ba fe daily Yoruba run o tomotomo tebi tebi .Ase wa
Good talk Tani Olorun. I made the same submission on Sokoti Tv yesterday that all religions should inaugurate their own laws. Now, don’t just fold your arms. You should mobilise the Isese faithfuls to get a lawyer and start codifying and writing laws for Isese religion. Christians too should do the same. Then take a step further and organise conference on it. These people are coming back with this Sharia thing. Believe it. If they say they are already building a sharia court in Lagos, it is most likely to be true.
Ofin ti afi nse eto ilu ati oro’aajé ilu ti ko ni si iyanję tabi abosi ni awon Musulumi npe ni ‘Shari’a! Gbogbo ęsin lo ni ofin, gbogbo won si jó ara won pęlu… Christianity ni Shari’a botilęję wipe awon omo lęyin Kristi ki telee awon ofin ęsin won. Ofi ilę Nigeria, ti Yoruba nfę ki a ma lo wa lati inu awon ofin ęsin na ni… bę ko yę ki agbe ofin ilu bori ofin Olohun Oba!
@ Dr Taniolorun,E Bawa Beere Lowo Awon Ilu Wonyi,Wipe Idagba Soke Nips IMO Ijinle Tabi Eko Ijinle wo Ni Sharia Law Mu wa Fun Awon Ara Ilu Won yi.Ibeere Mi Niyen
Bold and brilliant !
I watch him from New York every time every day…
Very brilliant guy His ability in yoruba language is fantastic and funny
Ikoja aye Awon omo ale mohammadu
Bawo ni ẹsin musulumi ṣe wa di ìjọba òṣèlú ile Nigeria, ọtọ l'ẹsin ọtọ ni ijọba. Ki awọn Musulumi lo so agbejẹ mọwọ ki wọn ma da ogun silẹ ni ilẹ yoruba.
They are using style ,if care is not taken,those people already knew that our amalgamation deal has expired,and now strategically trying to colonize us,we have to be seriously careful ooo,Isese agbewa ooo
I can now see the reasons why Late Chief Obafemi Awolowo gave free Education! Yoruba stands on its own and religion stands on their own.
God bless him I thought about it this morning
God bless you . Ile orisa àti ise ni ile babanla wa. Eda ti wa ko ni gbabode ni ile Yoruba. Awon onile ko ni gba fun awon eni ẹ gbé wọn. Isese lagba. Ifa ni o bori . Ifa ni o bori gbogbo wọn.
Awa o ni pofo a o ni rofo. Ifa a gba wa lowo eni ofo yi. Olodumare o ni jeka ri ibi àwọn ẹṣin pani pani
Say no to Serial law in Yoruba land 💯
Say no to islam. Esin ikonileru ni islamu
Abula-la-sisi,so funny 🤣🤣
Eledumare oba adeda aseda o mama was pelu yin nigba kugba lore kore Lori oro akin ton ti enu yin jade lodi si Sharia law oriburuku ti won fe gbewa sile Yoruba ti kole sese rara ati rara Tani olorun you are a man of courage God we continue be with you
Why suspended until further notice, it should be ban or cancel permanently / completely. We don’t want to hear any sharia court in any Yoruba land
👍 👍 👍 👍 👍
They want to use taqqiya
Kudos to you Tani Olohun, this is the kind of program you should be doing.
All Emilokan people can clearly see that Ahmed Bola Tiefnubu is a born wasted Yoruba man, next election he should voted out of the office.
This is Yorubaland, we are not Saudi or Muhammad slaves.
Yorubaland belong to Isese.
Use your brain. Can a man whose wife is a Christian and a pastor be thinking of instituting a sharia in Yorubaland?
Best for you, there should be isese court and Christian Court
Capital NO to SHARIA COURT in Yoruba Land!
Thank you Prof. Tani Olohun(PhD) ❤❤❤❤❤❤❤❤❤
Which PHD lmao 🤣 🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣
Gbogbo orile-ede ni agbaye ti won ti n'se ofin Sharia awon orile-ede bee ki roju kii ra'ye won oo si ki ni ilosiwaju tobe jubee lo. E ku ise iran wa oo.❤❤
Lootó? Saudi Arabia: ko si ilu to ni óro ati ifayabalę ti o to ni gbogbo ile Larubawa. Malaysia: igbe aiye to dun to laarinrin ni awon ori’lę ede ngbe o. Bhurtan: awon ara ilu yi kii sé wahala rara ki wo to jęun. Qatar: gbogbo wa la mo wipe ilu to ni ęwa ati óro bi ilu yi s’ówon ni agbegbe rę. Indonesia: ko si wahala ati pakaleke ni oro awon omo ilu yi rara, ifayabalę nbę ni’bę ti o ju ti gbogbo agbanla aiyé lo… ati awon ilu bę bę lo ti nlo Shari’a ninu ofin ilu won!
You're liar. You forgot to mention Syria, Iraq, Iran and Pakistan. Definitely, Isese court and Christian court will be approved and there will be common of different laws. Is that what you want because it will leads to community war because all the religion sectors are also entitled to establish their courts.
you just listed the most beautiful, peaceful and progressive countries… until Western imperialists (who happens to also be Christian nations🙄) invaded, destroyed, looted and breed young men for terrorism in order to establish their own authority and influence in those countries! Deep down in your heart you know it’s true. If all religions want to establish their own individual customs and laws, as long as they don’t conflict with states laws, and what is naturally good for everyone, what’s the problem with that? Abi you don’t know that even state laws came from God’s laws ni?
What kind of demon jumped into those trying to establish sharia law in Yorubaland? WE ARE YORUBAS.
We don't want suspension. What we want is permanent cancellation.
shame will not let them say cancelation
U are the best
Tani Olohun, I don't think the president and our Governors are in support of the Sharia court. Those people are stupid. Agba wole niti serin, akanmole niti eekan, aku sorinu niti adan, iran fulani, eru (slave) fulani ati awon alakatakiti esin omo yoruba o ni gberi mo ni ile yoruba lagbara Olodumare. Asee. More power to your elbow Prof. Tani Olohun. 👍 ❤❤❤
Awise afogbohun 🙏
I’m a Muslim and I say a big No to sharia law on our land we’re slave to nobody.
How many politicians in northern Nigeria have they used sharia courts.
Eledumare oni gbáfun won
God bless your efforts with success in Jesus name. Amen
You are right❤ Prof Tani Olorun
There will be no sharia law in our country ( Yoruba nation)
TANI OLOHUN
OLOHUN BLESS YOU
Sharia court ko le sele ni ile yoruba laelae.
No to SHARIA jungle justice system in YORUBA LAND
"Ofin awon abirun," much more like it! Awon oloriburuku, won fe so awa na di babiyanla!
Isese lagba court of Nigeria and Christian court of Nigeria
Tani olorun. You are the best in bringing out hidden facts and truth
A o gba Seria kan kan o ile Yoruba lawa
You're tooooooooo much thanks u 'jare, islam ti lule gbosiaaaaa
😂😂😂you no be muslim? 😂😂😂
God bless you my brother respect
Ori won lodaru
Awon oponu omo ale yoruba. Ala tikolese laillai ni. Omo iya, omo baba lawa nile Ootu Ife
Victoria Adejube. My dad God Almighty bless you sir ❤ good talk 🙏
Abula six😀😀😀😀.
The way you pronounce the name self they make me laugh.
🤣🤣
Abula ewedu
Abula gbegiri
Or
Abula seven
Abula eight
Etc😃😃😃😃
you no go kill person
😂😂😂 abula six
Six is the middle name. First name: Abula.🤣🤣
This guy is highly intelligent.
This is not a matter of suspension,no sharia law in Yoruba land,if you don’t want Religion war in Nigeria,both non radical Muslim,Christian and traditionalist will join their hands together to fight evil religion policy.
Sharia court o di gbere fa
bada ko gbodo gberi ni ile yoruba lailai
Yoruba nation.no going back
ori iya ati baba wa oo ni pada leyin wa ooo... ka mari ni! eewo orisa! Tani Olohun Aseda oo ni pada leyin re ooo! You are speaking on behalf of us all.
This guy is very wise ❤❤
SHARIA COURT KO LE WORK.
KO NI ṢẸLẸ LA'AGBARA ELEDUMARE.
Even ope kewu don't want it to work
Se Sharia Court lo tun kan, mu gbogbo eyiti awa ninu e yii, Eledua gbawa lowo awon olopolo lilo tan nse ijoba lewa lori ni Nigeria 🙏
No Saria law! We don’t want ni gbogbo ile ootu
Sharia law in Yorubaland is Baba ńlá àrífín. Never I repeat, never will there be a Sharia law in any part of Yorùbá land ✅✅✅🙌🙌🙌.
Yoruba nation no going back
Sharia Court? the biggest and unimaginable Taboo to be mentioned in the entire Land of Yorubas, Kilo wa de ti Afojudi ati Arifin nla yii tie wa poju fun Iran Omo-Alade bayi? O mase o, sugbon ohun kan to daju ni wipe gbogbo randanrandan yi nbo wa di'tan laipe ojo. Tani Olorun e ku eto o, Ajinde Ara too maa je o.
You be real mumu if you're any Oba and still practising esin ofo islamu.
SAY NO TO SHARIA COURT..IN SOUTHWEST OF NIGERIAN CITIZENS PLEASE
God bless you sir
Ekuise ooo eku eto klnse awon alfa yi tiwon ojeki ile yoeuba nlsinmi ilorin egbaki iseae se odun gemoja won esodi wahala mowon lowo efi olopa gbe won se eronu pe iru ojo bayi maawaye latise seria nile yoruba koleseesw ija lefe dasile
They must be playing
They are gentle when they are the minority.
We have to get Yoruba nation asap so we can tame extremism
Wan nsie wan de nsiere
Abula sisi
O funny 😂
TANI OLOHUN HAPPY XMAS OO
Awon Muslim iwa gbogbo ônon lati balê yoruba jê ni onni ore konkon latise fu ilê yoruba
Kaare, awon onile a gbe o, lase Edumare.
Gbogbo esin wa naa ma ni court ti won.
Sharia law court can never work in Lagos 💯💯👊 laye laye
It will not only fail inLagos state but even ondo and ekiti states.
After the failure of fulani herdsmen in Yoruba land, their next try is Sharia. Ofò kannáà ni Sharia máa ṣe.
They can't try it in ekiti we are waiting for them to try it in oyo state
Àfilọ̀ l'orun orí kẹ̀ké̩, wọn fi lọ ẹ̀yin Ọmọ Yorùbá ni. Àyé gb'èkùlù Ọ̀dàn tán ofé̩ ni pọn l'áyà bi ìrá. Àwa ò ni gbàgbà ku gbà o.
ÒFIN SHARIAH TI LA ẸYIN ONÍṢẸṢẸ LÓHÙN. A NÍ KÍ Ẹ JẸ́ KÍ Á GBA ORILẸ-ÈDÈ YORÙBÁ, ṢUGBỌN Ẹ NÍ KÒ KÀN YÍN.
Were ni yin sir. Eegbadun
@favourwilliam8510 TIYIN TI RUN JÉGÉ JÉGÉ SIR
TIYIN TI DOGUN SIR
Aubula Aziz 😂😂😂😂
E se o Tani Olorun. Eyin Sotosoro E dide e gbohun soke o .Awon Alale ile Yoruba E dide o .E pa gbogbo Eni to ba fe daily Yoruba run o tomotomo tebi tebi .Ase wa
This ..people with problems..make they go too ..mecca now 😢
I too like ibo people
I love you brother
YORUBA NATIONA NO GOING BACK
Good 💪💪💪🇳🇬
Abula 6️⃣
Oba oluwo
Akeugbagold
Mufuti dawuud ilu iwo
Awọn were ti wọn şe agbaręru sharia law niyęn
CUSTOMARY COURT WA NILĘ WA ALREADY JARE BABA MI
Ko de ni dada fun gbogbo won ti won ni owo ninu oriburuku sharia law ni Ile Yoruba.
Awon alale yio ko oju ija si gbogbo won ni Ase Edumare.
Which job will the court create for people? Absolute nonsense
Ema deke
Good talk Tani Olorun. I made the same submission on Sokoti Tv yesterday that all religions should inaugurate their own laws. Now, don’t just fold your arms. You should mobilise the Isese faithfuls to get a lawyer and start codifying and writing laws for Isese religion. Christians too should do the same. Then take a step further and organise conference on it. These people are coming back with this Sharia thing. Believe it. If they say they are already building a sharia court in Lagos, it is most likely to be true.
Am a Muslim, I say no to shariah law.
Keep helping us to state it clear to your people.
We say no!
If Ur a Muslim you should accept Sharia, remember Islam is a religion of peace
There is Shari'a court in Ilorin after driving past Kwara state police command.
Mufty enupor FC 😂😂😂
👍👍
There is a sharia court of appeal in Ilorin opposite the governor's office
Is in active unlike those in the North, which means it can't work in Yoruba land.
Werey lo do iya awon werey omo eru...
Oloriburuku niwon
There is sharia court is in Ilorin oo not too far to high court
❤❤❤
Say NO To SHARIA LAW in YORUBA land. Not acceptable
What about the one commisioned by Imam of Ogbomosho
Ofin ti afi nse eto ilu ati oro’aajé ilu ti ko ni si iyanję tabi abosi ni awon Musulumi npe ni ‘Shari’a! Gbogbo ęsin lo ni ofin, gbogbo won si jó ara won pęlu… Christianity ni Shari’a botilęję wipe awon omo lęyin Kristi ki telee awon ofin ęsin won. Ofi ilę Nigeria, ti Yoruba nfę ki a ma lo wa lati inu awon ofin ęsin na ni… bę ko yę ki agbe ofin ilu bori ofin Olohun Oba!
Egba Saudi lo now
Se dandan ni..
No to Sharia law in Yoruba land
Ema je ki won da sharia were Kan le
Sharia court for Iwo and ilorin
Thanks so much tani olorun see how your formal name been called by you abula zix
💯💯🙏🏿
They want to start from oyo so that they can implement the law in you
Christian Court, Isese Court and Sharia Court 😂😂😂
Awon Oloriburuku lasan lasan.
AARẸ OPITAN LAJI ABASS KO TI SỌRỌ NIPA ỌRỌ SHARIA YI. KILODE?
Hypocrite ni man yen
No Tori omo eru ni
Obayeje ni!
I have stopped following or watching his stupid and hypocrite program
@ Dr Taniolorun,E Bawa Beere Lowo Awon Ilu Wonyi,Wipe Idagba Soke Nips IMO Ijinle Tabi Eko Ijinle wo Ni Sharia Law Mu wa Fun Awon Ara Ilu Won yi.Ibeere Mi Niyen
Eru court
Governors should not allowed them to do dat
Musulumi lo gor ju lagbaye, esin ikonileru esin jagidijagan ni islamu. Wan fe bayewa je ti wan se baye awon hausas je. Awa o ni gba fu wan.
Elewon lawon to sagba teru re. Suspension or cancelation?
😅😅😅😅😅