Ojú Kálé: Àwọn Ọmọ Naijiria Fi Èrò Wọn Hàn Nípa Ìfẹ̀hónúhàn Tí Àwọn Kan Ń Pète Rẹ̀

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 11 вер 2024
  • A bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ nípa awuyewuye tó ń lọ láàrin ìlú wí pé àwọn ará ìlú kan fẹ́ ṣe ìwọ́de ìfẹ̀hónúhàn látàrí bí ètò ọrọ̀ ajé Nàìjíríà ṣe ti ń dojú bolẹ̀ lásìkò ìjọba Ààrẹ Bọ́lá Ahmed Tinubu.
    Àwọn kan nínú àwọn ará ìlú faramọ́ ìwọ́de ọ̀hún kí ìjọba lè ṣe ohun tárá ìlú ń fẹ́, nítorí bá a bá dákẹ́, tara ẹni a máa báni dákẹ́, nígbà tí àwọn mìíràn kò sì faramọ́ kí ìwọ́de náà wáyé kí àwọn oníjàgídíjàgan má baà lò ó fún ìdàlúrú àti bíba dúkìá jẹ́.

КОМЕНТАРІ • 2

  • @ModupeEsho
    @ModupeEsho Місяць тому

    Alaja my regards to your sister iya kari

  • @ModupeEsho
    @ModupeEsho Місяць тому

    Alaja Sekinat till when