- 11
- 12 512
OLORIRE T.V LIVE BABA RESEARCH
Приєднався 29 кві 2024
Відео
haa leyin ti Imam Teliat tuba lowo mudiru moricas tan egbo nkan totun fi moricas we ogao
Переглядів 1,6 тис.10 днів тому
haa leyin ti Imam Teliat tuba lowo mudiru moricas tan egbo nkan totun fi moricas we ogao
Aare onakankanfo ni odun Ogbomosho cradle carnival 2024 won gbe osuba rande fori Ade
Переглядів 59511 днів тому
Aare onakankanfo ni odun Ogbomosho cradle carnival 2024 won gbe osuba rande fori Ade
wa woo ijapa ilu iseyin toti lo 400years laye pelu awon ohun Ara tomu wo ilu iseyin
Переглядів 7115 днів тому
wa woo ijapa ilu iseyin toti lo 400years laye pelu awon ohun Ara tomu wo ilu iseyin
omo tie pon nigbayen ese re ti wole oooo IPO yen ju ojo Ori re loo, Oro nla re oooo lati Enu wakilu
Переглядів 1,7 тис.16 днів тому
omo tie pon nigbayen ese re ti wole oooo IPO yen ju ojo Ori re loo, Oro nla re oooo lati Enu wakilu
ewa wo bi Imam Ogbomosho se sadua ibere ni carnival Ati bose yipo abata ile ebo nje o ba Sunnah mu
Переглядів 5 тис.19 днів тому
ewa wo bi Imam Ogbomosho se sadua ibere ni carnival Ati bose yipo abata ile ebo nje o ba Sunnah mu
haaaaa ASE Alfa ni baba ogbagba eyin Alabosi Eni ku re gbo igbiyanju baba wa yii ni oju Eko mimo
Переглядів 74426 днів тому
haaaaa ASE Alfa ni baba ogbagba eyin Alabosi Eni ku re gbo igbiyanju baba wa yii ni oju Eko mimo
haaa wo aduru dukia to je 753 duplex ile GBE ti oga ile ifowo pamo c.b.n ko pamo oga oooo
Переглядів 45Місяць тому
haaa wo aduru dukia to je 753 duplex ile GBE ti oga ile ifowo pamo c.b.n ko pamo oga oooo
motowo bo iwe lodo secretary soun wipe mio ni kuro lai gbase lowo oba
Переглядів 1,8 тис.Місяць тому
Egbo Oro lati enu Imam Ogbomosho Lori awon iwe ti o sign lodo oba
dokuturu bitibawo laisepe oyinbo sare(sick) iro lasan ni 🤣
Переглядів 267Місяць тому
Dokuturu bitibawo laisepe oyinbo sare 🤣 (sick) iro lasan ni 🤣 P.H.D modiru moricas ti soro soke oooo
@Adeyemiolorire
Переглядів 313Місяць тому
Ashiri nla tu Lori Oro mosalasi nla tilu Ogbomosho baba Parakoyii Adini tile Ogbomosho lotu winrinwinrin
You're a liar.
Esin Islam esin ododo eniti o ba fe ko gbo.Imam nso ododo fun yin laibu enikeni
😊Bobo yii, try ko beru Olohun. Ati ojo ti wa pade Olohun re o.
Why not pray for this guy ... You should observe that he is not well. Pray for him to find perfect healing.
Imam Yunus Toliat Ayilara The Second as come and he's comes to stay.... Long life too ologbomosho of Ogbomosho land ALH Dr Al Imam Yunus Toliat olusina Ayilara The Second 🙏🙏 Sheuuuuuuu Sheuuuuuuu
Iro ni gbgb won pa Oro olohun kise iro Awon ni opuro Ati Agba Yahoo fun awon omo ijo won
Ibaje eniyan
Toliat arobafin, must become a non-person to the stool. he cant and should be doing only his islamic allah sharia and jihad stuffs. He's not a member of the royal household and have a replacement for that job.
U should have done well your research before posting it
Imam is right on
Oloriburuku TV
@@kolawoleayilara9714 inshallah Ramon bio se ri fun eee ni niyen olorire lawa nse
Awon èru shigidi allah
Arange
Hhmmm
Jazakallah Khaeran Baba alubarika Thanks for this speech E
People can repent and recant on what they've done in the past. You surely have that concept in your religion too.
OKUNRIN YI...ORIRE TI FOKA.
Baba,yi koyeki Ologbon magborore,rara kantankantan,tipojuelo,Gbesenbo Nidi hiso otito,ok,Alabosi konjere
Quran tipari oroayeyin sidi ofo Iron+ote+Hilojuti Gbogbore lowaninu Ayeyin Iyanduro deyin tiekobatuba kietoku ok
Emi o ri tabi gbo bi imam se sadura o.iro ni iwo okunrin yi pa mo imam.
Baba Parakoyi bi e se so yi iwa Alaimore ni eleyi, pelu ogo Olohun, Olohun Oba Allahu Rahaman yio fi Imam bori 9:52 gbogbo yin Amina.
May ALLAH continue to bless Imam Tolihat, the chief Imam of blessed Ogbomosho land
Ibaje eniyan kodase oluwaduro asebaje o nigbayi baba imam wahinnaju dana lahumuli galibuna
You are a liar. Is he refer to Carnival as ọdún ẹbọ. Àtúnbọ̀tán rẹ ni ki o ma ranti. From all what you showed where is the vedio where the Imam is praying at a carnival? Do you think you can turn false to truth. Well, end shall tell.
Ejekia ranti atubotan o Leave Imam alone Let Allah judge him
Epe yi naa ni shaa
Rubbish talk, you don't have a job
Imam Ogbomoso na 2face.
Oponu ni ogbeni imman yiii
Robesse
Loowa ise se
Odo Oro ni imam noso ki lode ti eya alabossi bayii inchallah awom omo re Oro alatako titi layelaye
Opolore tiyioro
You are a fool
Na'am! Ija ILARA ni kii tan boro o! No 1. Awon video/pictures ti e fi han yi ko ko se atileyin oro Imam ti e n so nipa pe (a) Nibo ni Imam ti se Adua Ibere nibe?! Awon eegun la koko ri ti won n jo! Ao ri video Adua Ibere ati eni to see depo pe ao waa maa gbo bo se n se Adua naa! No 2. Ibiti e ni won ti n yipo Oosa Abata (abi kin le pee?), ao ri Imam nibe, sugbon a ri Kabiesi! So, ibaje Imam ti e fee se nibi yi ko wole rara! Then to ba je pe Carnival lasan ni won fee se, ko si ofin Islam to ta koo pe ki Imam ma se Adua ibere nibe o. Ka waa so pe Imam wa nibe looto ni, itumo to fun wa ni pe bi Imam ba so pe oun o le lo sibe (nitori esin toun), sugbon boya latari ase Kabiesi, eyin yi naa lee maa so pe o r'oba fin! Bi a ba sakieyesi gan n, Kabiesi paapaa ti a ri yi, inu won ko dun si nkan ti eon n se yi nitiri pe o lodi di esin won, sugbon won gba kamu nitori aayee won! Mo mo pe bi yoo se ri lokan Imam naa niyen ti Imam ba tie wa nibe rara! Sugbon pelu bi nkan se ri niisinyi, imam ti ja ara re gba, ko s'eni to le tie da aba lati fi iru e lo Imam mo depo pe won o so pe ko loo maa yipo okuta kan!
Iwo ni o ri Imam. Awon eniyan ri Imam ti o yika abata.
Oponu ni iwo bobo yi se ebo ni caniva ni eku to no idi abosi
Werey oloribu or what do you call yourself. We can't see imam at where they are circulating the abata
Olorun ase idajo re
Gbogbo bi e se n se ibaje Imam, bee ni oore Olohun n po si ninu aye won. Ibaje eniyan ko da ise Oluwa duro. Inshallah, Imam ni o leke gbogbo yin amin.
Oponu nie oro oye e rara, continue.
IRO RE TI POJU
ORI RE KOPE
ODODO ORO NI IMMAM SO
Eku ise, Olorun a wa pelu yin. More wisdom In Sha Allah. Ogbomosho a gbe wa L'oruko Jesu. Awon alabosi loju ma ti lagbara Olorun.
HAAAAAAA 😂😂
IRO YI NAN NII 😂😂 KILODE
Eyin re to gbe omo pon yen oni lakaye rara, se ajodun ebo ni won hun se ni oponu, ohun to je ko je ko gbon rara
Jo kini isoro re ti iwo omon ju ki omon pegan lo amon kojowa koju emon se abosi yin lo esan detan
Se egan ni yen abi fact?
Eku ise
Jo se iwo je onisese ni abi baba Imam Ni ki won Mon se kanifa oje kuro nibi abosi
Must Imam join them before and he never preached against it but when the table turn round is now seeing at bad. Imam is not straight forward on so many.
Irọ tí báyé bọbọ yen jẹ 😅😅 Opurọ gbáà ni