Ceyoleng
Ceyoleng
  • 6
  • 187 800
ALO IJAPA OLOGBON EWE ABALA KARUN UN - CEYOLENG
ÀLÓ ÌJÀPÁ OLÓGBÓN ÈWÉ: ÌJÀPÁ TAN ERIN WO ÌLÚ: Abala karùn-ún: Níkeyìn, ìjàpá fi ogbón èwé rè mú erin wo inú ní ibi tí ó ti réyìn erin (THE STORY OF THE CRAFTY TORTOISE: THE TORTOISE USED HIS WILES TO GET THE ELEPHANT TO TOWN: Episode five: Eventually, the tortoise used his wiles to get the elephant to the Oba's palace where he got rid of the elephant)
Переглядів: 40 891

Відео

ÀLÓ ÌJÀPÁ OLÓGBÓN ÈWÉ | ABALA KERIN - CEYOLENG
Переглядів 61 тис.4 роки тому
ÀLÓ ÌJÀPÁ OLÓGBÓN ÈWÉ: ÎJÀPÁ TAN ERIN WO ÎLÚ: Abala kerin: Léyìn tí gbogbo ètò tó jé dandan láti se ti parí, ìjàpá forí lé inú igbó láti wá erin rí. Nígbà tó fojú ko erin lójú, ó bèrè sí pón on, ó sì n tàn án kí ó lè gbà láti wá je Oba tuntun. Léyìn náà, wón mú ònà ìlú pòn.(THE STORY OF THE CRAFTY TORTOISE: THE TORTOISE USED HIS WILE'S TO GET THE ELEPHANT TO TOWN: Episode four: After completing...
ALO IJAPA OLOGBON EWE ABALA KETA - CEYOLENG
Переглядів 29 тис.4 роки тому
ALO IJAPA OLOGBON EWE: IJAPA TAN ERIN WO ILU: Abala keta: Oba se ipade pelu awon ara ilu ni aafin re lori ona lati fi opin si iwa ibaje erin. Ijapa leri pe oun le reyin erin, o si lo si aafin ni ojo keji ipade lati so fun Oba ete ti oun yo pa lati reyin erin (THE STORY OF THE CRAFTY TORTOISE: THE TORTOISE USED HIS WILES TO GET THE ELEPHANT TO TOWN: Episode three: The Oba had a meeting with the ...
ALO IJAPA OLOGBON EWE ABALA KEJI - CEYOLENG
Переглядів 12 тис.4 роки тому
ALO IJAPA OLOGBON EWE:IJAPA TAN ERIN WO ILU:Abala Keji:Awon ara ilu lo fi ehonu han lodo Oba lori iwa ibaje Erin. Oba pa ase fun alagogo re pe ki o lu agogo kiri ilu lati kede apero gbogbo ara ilu ni aafin oun ni ojo keji lori oro naa(THE STORY OF THE CRAFTY TORTOISE:THE TORTOISE USED HIS WILES TO GET THE ELEPHANT TO TOWN:Episode two: The representatives of the townspeople complained to the Oba...
ALO IJAPA OLOGBON EWE ABALA KIN NI : IJAPA TAN ERIN WO ILU - CEYOLENG
Переглядів 36 тис.4 роки тому
Abala kinni ni kikun: Erin hu iwa ibaje ni awujo, awon ara ilu si pinnu lati fi ehonu han si Oba(THE STORY OF THE CRAFTY TORTOISE:THE TORTOISE USED HIS WILES TO GET THE ELEPHANT TO TOWN:Episode one in full: The behaviour of the Elephant in the community was destructive and the townspeople decided to complain to the Oba)
ALO IJAPA OLOGBON EWE - CEYOLENG
Переглядів 9 тис.4 роки тому
LARA ONA TI AWON YORUBA N GBA KO AWON OMODE NI EKO ALO WA.IJAPA NI YORUBA SABA MAA N LO GEGE BI EDA ITAN. ERIN N DA WON LAAMU NINU ILU.AWON ARA ILU FORIKORI LATI FI OPIN SI IDAAMU ERIN.

КОМЕНТАРІ